ملة الإسلام

السورة 111 · 5 آية · Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

سورة المسد باللغة اليوروبا

السورة بالعربية مع التفسير استمع إلى سورة المسد (1,267 قارئاً)
مكيةسورة المسد٥ آية

بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ

تَبَّتۡ يَدَآ أَبِي لَهَبٍ وَتَبَّ ١Ọwọ́ Abu-Lahab méjèèjì ti ṣòfò. Òun náà sì ṣòfò مَآ أَغۡنَىٰ عَنۡهُ مَالُهُۥ وَمَا كَسَبَ ٢Àwọn dúkìá rẹ̀ àti ohun tí ó ṣe níṣẹ́ (ìyẹn, àwọn ọmọ rẹ̀) kò sì níí rọ̀ ọ́ lọ́rọ̀ (níbi ìyà) سَيَصۡلَىٰ نَارًا ذَاتَ لَهَبٍ ٣Ó sì máa wọ inú Iná eléjò fòfò وَٱمۡرَأَتُهُۥ حَمَّالَةَ ٱلۡحَطَبِ ٤Àti ìyàwó rẹ̀, aláàárù-igi-ìṣẹ́pẹ́ ẹlẹ́gùn-ún, (ó máa wọná) فِي جِيدِهَا حَبۡلٌ مِّن مَّسَدِۭ ٥Igbà-ọ̀pẹ pọ̀npọ̀nràn máa wà ní ọrùn rẹ̀ (nínú Iná)

الترجمة: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.