Millat al-Islam

Chapter 105 · 5 verses · Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Surah Al-Fil in Yoruba

Arabic with tafsir Listen to Surah Al-Fil (851 reciters)
Meccanسورة الفيل5 verses

بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ

أَلَمۡ تَرَ كَيۡفَ فَعَلَ رَبُّكَ بِأَصۡحَٰبِ ٱلۡفِيلِ ١Ṣé o ò rí bí Olúwa rẹ ti ṣe ọ̀rọ̀ ìjọ elérin ni أَلَمۡ يَجۡعَلۡ كَيۡدَهُمۡ فِي تَضۡلِيلٍ ٢Ṣé kò sọ ète wọn di òfo bí وَأَرۡسَلَ عَلَيۡهِمۡ طَيۡرًا أَبَابِيلَ ٣Ó sì rán àwọn ẹyẹ níkọ̀níkọ̀ sí wọn تَرۡمِيهِم بِحِجَارَةٍ مِّن سِجِّيلٍ ٤Wọ́n ń jù wọ́n ní òkúta amọ̀ (t’ó ti gbaná sára) فَجَعَلَهُمۡ كَعَصۡفٍ مَّأۡكُولِۭ ٥Ó sì sọ wọ́n di bíi èrúnrún koríko àjẹkù gbígbẹ

Translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.