Millat al-Islam

Chapter 104 · 9 verses · Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Surah Al-Humaza in Yoruba

Arabic with tafsir Listen to Surah Al-Humaza (1273 reciters)
Meccanسورة الهمزة9 verses

بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ

وَيۡلٌ لِّكُلِّ هُمَزَةٍ لُّمَزَةٍ ١Ègbé ni fún gbogbo abúnilójú-ẹni, abúnilẹ́yìn-ẹni ٱلَّذِي جَمَعَ مَالًا وَعَدَّدَهُۥ ٢ẹni tí ó kó owó jọ, tí ó sì kà á lákàtúnkà (láì ná an fẹ́sìn) يَحۡسَبُ أَنَّ مَالَهُۥٓ أَخۡلَدَهُۥ ٣Ó ń lérò pé dájúdájú dúkìá rẹ̀ yóò mú un ṣe gbére (nílé ayé) كـَلَّاۖ لَيُنۢبَذَنَّ فِي ٱلۡحُطَمَةِ ٤Rárá (kò rí bẹ́ẹ̀). Dájúdájú wọ́n máa kù ú lókò sínú Hutọmọh ni وَمَآ أَدۡرَىٰكَ مَا ٱلۡحُطَمَةُ ٥Kí sì ni ó mú ọ mọ ohun t’ó ń jẹ́ Hutọmọh نَارُ ٱللَّهِ ٱلۡمُوقَدَةُ ٦(Òhun ni) Iná Allāhu tí wọ́n ń kò (t’ó ń jò geregere) ٱلَّتِي تَطَّلِعُ عَلَى ٱلۡأَفۡـِٔدَةِ ٧èyí tí ó máa jó (ẹ̀dá) wọ inú ọkàn lọ إِنَّهَا عَلَيۡهِم مُّؤۡصَدَةٌ ٨Dájúdájú wọ́n máa ti (àwọn ìlẹ̀kùn) Iná pa mọ́ wọn lórí pátápátá فِي عَمَدٍ مُّمَدَّدَةِۭ ٩(Wọ́n máa wà) láààrin àwọn òpó kìrìbìtì gíga (nínú Iná)

Translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.