Millat al-Islam

Chapter 112 · 4 verses · Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Surah Al-Ikhlas in Yoruba

Arabic with tafsir Listen to Surah Al-Ikhlas (1391 reciters)

بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ

قُلۡ هُوَ ٱللَّهُ أَحَدٌ ١Sọ pé: "Òun ni Allāhu, Ọ̀kan ṣoṣo ٱللَّهُ ٱلصَّمَدُ ٢Allāhu ni Aṣíwájú (tí ẹ̀dá ní bùkátà sí, tí Òun kò sì ní bùkátà sí wọn) لَمۡ يَلِدۡ وَلَمۡ يُولَدۡ ٣Kò bímọ. Wọn kò sì bí I وَلَمۡ يَكُن لَّهُۥ كُفُوًا أَحَدُۢ ٤Kò sì sí ẹnì kan tí ó jọ Ọ́." èyí ni a mọ̀ sí “rọbbu-ssamọ̄wāt wal-’ard wa mọ̄ baenahumọ̄”. Ìdí nìyí tí a ò fi túmọ̀ “Allāhu” sí “Ọlọ́hun”. Nínú èdè Yorùbá kò fẹ́ẹ̀ sí ìtúmọ̀ tí a fọkàn balẹ̀ sí fún ọ̀rọ̀-orúkọ ńlá náà “Allāhu” àfi lílo ọ̀rọ̀-orúkọ kan èyí tí àwọn Yorùbá máa ń lò ní ọjọ́un àná fún “Ọlọ́hun”. Ṣíṣe bẹ́ẹ̀ sí máa mú àríyànjiyàn lọ́wọ́. Nítorí náà

Translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.