Millat al-Islam

Chapter 113 · 5 verses · Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Surah Al-Falaq in Yoruba

Arabic with tafsir Listen to Surah Al-Falaq (1299 reciters)
Meccanسورة الفلق5 verses

بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ

قُلۡ أَعُوذُ بِرَبِّ ٱلۡفَلَقِ ١Sọ pé: "Mo sá di Olúwa òwúrọ̀ kùtùkùtù مِن شَرِّ مَا خَلَقَ ٢níbi aburú ohun tí Ó dá وَمِن شَرِّ غَاسِقٍ إِذَا وَقَبَ ٣àti níbi aburú òru nígbà tí ó bá ṣóòkùn وَمِن شَرِّ ٱلنَّفَّٰثَٰتِ فِي ٱلۡعُقَدِ ٤àti níbi aburú àwọn (òpìdán) t’ó ń fẹnu fátẹ́gùn túẹ́túẹ́ sínú àwọn ońdè وَمِن شَرِّ حَاسِدٍ إِذَا حَسَدَ ٥àti níbi aburú onílara nígbà tí ó bá ṣe ìlara

Translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.