Millat al-Islam

Chapter 109 · 6 verses · Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Surah Al-Kafirun in Yoruba

Arabic with tafsir Listen to Surah Al-Kafirun (773 reciters)

بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ

قُلۡ يَٰٓأَيُّهَا ٱلۡكَٰفِرُونَ ١Sọ pé: "Ẹ̀yin aláìgbàgbọ́ لَآ أَعۡبُدُ مَا تَعۡبُدُونَ ٢Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún وَلَآ أَنتُمۡ عَٰبِدُونَ مَآ أَعۡبُدُ ٣Ẹ̀yin náà kò jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún وَلَآ أَنَا۠ عَابِدٌ مَّا عَبَدتُّمۡ ٤Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ jọ́sìn fún sẹ́ وَلَآ أَنتُمۡ عَٰبِدُونَ مَآ أَعۡبُدُ ٥Ẹ̀yin náà kò kú jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún لَكُمۡ دِينُكُمۡ وَلِيَ دِينِ ٦Tiyín ni ẹ̀sìn yín, tèmi sì ni ẹ̀sìn mi

Translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.