Millat al-Islam

Chapter 108 · 3 verses · Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Surah Al-Kawthar in Yoruba

Arabic with tafsir Listen to Surah Al-Kawthar (810 reciters)
Meccanسورة الكوثر3 verses

بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ

إِنَّآ أَعۡطَيۡنَٰكَ ٱلۡكَوۡثَرَ ١Dájúdájú Àwa fún ọ ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ oore فَصَلِّ لِرَبِّكَ وَٱنۡحَرۡ ٢Nítorí náà, kírun fún Olúwa rẹ, kí o sì gúnran (fún Un) إِنَّ شَانِئَكَ هُوَ ٱلۡأَبۡتَرُ ٣Dájúdájú, ẹni t’ó ń bínú rẹ, òun ni kò níí lẹ́yìn

Translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.