Arabic with tafsir
Listen to Surah Al-Nas (1315 reciters)
بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ
قُلۡ أَعُوذُ بِرَبِّ ٱلنَّاسِ ١Sọ pé: "Mo sá di Olúwa àwọn ènìyàn مَلِكِ ٱلنَّاسِ ٢Ọba àwọn ènìyàn إِلَٰهِ ٱلنَّاسِ ٣Ọlọ́hun àwọn ènìyàn مِن شَرِّ ٱلۡوَسۡوَاسِ ٱلۡخَنَّاسِ ٤níbi aburú (Èṣù) oníròyíròyí, olùsásẹ́yìn (fún ẹni t’ó bá dárúkọ Allāh) ٱلَّذِي يُوَسۡوِسُ فِي صُدُورِ ٱلنَّاسِ ٥(Èṣù ni) ẹni tí ó ń kó ròyíròyí sínú àwọn ọkàn ènìyàn مِنَ ٱلۡجِنَّةِ وَٱلنَّاسِ ٦(Èṣù náà) wà nínú àlùjànnú àti ènìyàn
Translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.