Millat al-Islam

Chapter 94 · 8 verses · Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Surah Al-Inshirah in Yoruba

Arabic with tafsir Listen to Surah Al-Inshirah (1282 reciters)
Meccanسورة الشرح8 verses

بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ

أَلَمۡ نَشۡرَحۡ لَكَ صَدۡرَكَ ١Ṣé A ò ṣípayá igbá-àyà rẹ fún ọ bí وَوَضَعۡنَا عَنكَ وِزۡرَكَ ٢A sì gbé ẹ̀ṣẹ̀ rẹ kúrò lọ́rùn rẹ ٱلَّذِيٓ أَنقَضَ ظَهۡرَكَ ٣èyí tí ó wọ̀ ọ́ lọ́rùn. àmọ́ tí onítọ̀ún padà gba ’Islām ìbáà jẹ́ pé ó gbà á ní òwúrọ̀ وَرَفَعۡنَا لَكَ ذِكۡرَكَ ٤A sì gbé ìrántí orúkọ rẹ ga fún ọ فَإِنَّ مَعَ ٱلۡعُسۡرِ يُسۡرًا ٥Nítorí náà, dájúdájú ìdẹ̀kùn wà lẹ́yìn ìnira إِنَّ مَعَ ٱلۡعُسۡرِ يُسۡرًا ٦Dájúdájú ìdẹ̀kùn wà lẹ́yìn ìnira sẹ́ فَإِذَا فَرَغۡتَ فَٱنصَبۡ ٧Nítorí náà, nígbà tí o bá bùṣe (lórí ọ̀kan), gbìyànjú (òmíràn) وَإِلَىٰ رَبِّكَ فَٱرۡغَب ٨Ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ sì ni kí o ṣojú kòkòrò oore sí

Translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.