Millat al-Islam

Chapter 103 · 3 verses · Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Surah Al-Asr in Yoruba

Arabic with tafsir Listen to Surah Al-Asr (1268 reciters)
Meccanسورة العصر3 verses

بِسۡمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحۡمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ

وَٱلۡعَصۡرِ ١Allāhu búra pẹ̀lú àkókò ìrọ̀lẹ́ ayé إِنَّ ٱلۡإِنسَٰنَ لَفِي خُسۡرٍ ٢Dájúdájú ènìyàn wà nínú òfò إِلَّا ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَعَمِلُواْ ٱلصَّٰلِحَٰتِ وَتَوَاصَوۡاْ بِٱلۡحَقِّ وَتَوَاصَوۡاْ بِٱلصَّبۡرِ ٣Àyàfi àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n ṣe àwọn iṣẹ́ rere, tí wọ́n sọ àsọtẹ́lẹ̀ òdodo láààrin ara wọn, tí wọ́n sì tún sọ àsọtẹ́lẹ̀ sùúrù láààrin ara wọn

Translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni.